Aller au contenu principal





Text submitted to CC-BY-SA license. Source: by Wikipedia (Historical)


Jùmọ̀kẹ́ Ọdẹ́tọ́lá


Jùmọ̀kẹ́ Ọdẹ́tọ́lá


Ọlájùmọ̀lẹ́ Ọdẹ́tọ́lá (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹwàá) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lédè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n ní kété tó dára pọ̀ mọ́ tí èdè Yorùbá ní ìràwọ̀ rẹ̀ tàn.

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

Jùmọ̀kẹ́ kàwé gírámà rẹ̀ ní Abẹ́òkúta Grammar School. Ó kàwé gboyè dìgírì rẹ̀ ní ifáfitì tí Ajayi Crowther University, níbi tí ó ti gbà ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ìfitétí àti ìbánisọ̀rọ̀ nípa lílo ẹ̀rọ ìgbàlódé, kọ̀m̀pútà, lẹ́yìn èyí, ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Federal University of Agriculture, Abẹ́òkúta, níbi tí ó ti kàwé gboyè dìgírì kejì nínú ìmọ̀ ìjìnlè kọ̀m̀pútà.

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀

  • Somewhere in the Dark
  • Glitterati
  • Bíńtà Òfegè
  • Heroes and Zeros
  • Lágídò
  • Bachelor's Eve
  • Alakiti
  • HigiHaga
  • Tinsel
  • The Return Of HigiHaga
  • Family Ties
  • Kanipe (2017)
  • Wetin Women Want (2018)

Àwọn Ìtọ́kasí


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Jùmọ̀kẹ́ Ọdẹ́tọ́lá by Wikipedia (Historical)


Special Jollof


Special Jollof


Jollof Pataki jẹ fiimu awada romantic ti Ilu Naijiria 2020 kan. Ti ṣejade ati oludari nipasẹ Emem Isong ; Starring Joseph Benjamin, Uche Jombo ati Femi Adebayo ni awọn ipa asiwaju. Fiimu naa jẹ pataki ti a ya ni Nigeria ati Amẹrika. Akori ti fiimu naa ti ṣeto bi itan ifẹ, pẹlu iṣiwa ni abẹlẹ. Fiimu naa ti tu silẹ ni ọjọ 14 Oṣu Keji ọdun 2020 ni ibamu pẹlu Ọjọ Falentaini ati pẹlu ayẹyẹ ti oṣu Itan Dudu ni Amẹrika.

Simẹnti

  • Josefu Benjamini
  • Uche Jombo
  • Femi Adebayo
  • DJ Kelblizz
  • John Macag
  • Magdalen Vaughn
  • Bukky Wright
  • Robert Peters
  • Chiwetalu Agu
  • Perez Egbi

Afoyemọ

Akoroyin obinrin alawo funfun kan ara ilu Amerika ti o soji leyin ipinya pelu ololufe re bere ise apamowo ni ile onje Naijiria lati fi idi re mule pe awon omo Naijeria n gbe lo si orile-ede Amerika lonakona. Lẹhinna o ṣubu ni ifẹ pẹlu ọmọkunrin Naijiria kan.

Awọn itọkasi

Ita ìjápọ

  • Special Jollof , (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)

Giuseppe Zanotti Luxury Sneakers


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Special Jollof by Wikipedia (Historical)


Wale Ojo


Wale Ojo



Wale Ojo jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Britain. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣẹ láti ìgbà tó wà lọ́mọdé lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán. Ó tẹ̀síwájú láti máa ṣe eré ní UK àti Nàìjíríà. Ó bọ́ sí gbàgede ní ọdún 1995 fún kíkópa tí ó kópa nínú fíìmù The Hard Case. Ó gba àmì ẹ̀yẹ fún òṣèrékùnrin tó dára jù lọ ní ọdún 2012 ní 2012 Nigeria Entertainment Awards.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

Ọjọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré láti ọmọdé. Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́jọ, ó bá Akin Lewis ṣiṣẹ́ tí ó ṣe agẹrun nínú eré why worry lórí NTA Ibadan ní ọdún 1980. Nígbà tí ó pé ọmọdún méjìlá, ó kó lọ sí England pẹ̀lú àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ níbi tí ó ti lọ ilé-ìwé gíga.

Ojo gbóríyìn fún ìyá rẹ̀ tó jẹ́ òṣèré tí ó sì ṣe àtìlẹ́yìn fún nínú iṣẹ́ òṣèré rẹ̀, ó sì tún mẹ́nuba àwọn èèyàn bíi Chief Wale Ogunyemi, Tunji Oyelana, akọ̀wé ìtàn Wole Soyinka, àti Zulu Sofola gẹ́gẹ́ bí àwọn ẹni tí ó ràn án lọ́wọ́.

New Nigeria Cinema

Ọjọ́ dá New Nigeria Cinema ṣílẹ̀, èròǹgbà rẹ̀ sì ni láti mú kí àwọn fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dára si. New Nigeria Cinema ti ṣe ìgbàlejò ìwo fíìmù àti ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ní British Film Institute ní London ní ọdún 2010.

Àwọn iṣẹ́ rẹ́

TV programs

Films

Theatre

Àwọn àmì-ẹyẹ rẹ̀

Àwọn Ìtọ́kasí

Giuseppe Zanotti Luxury Sneakers

Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Wale Ojo by Wikipedia (Historical)


Eku Edewor


Eku Edewor


Georgina Chloe Eku Edewor-Thorley, tí a mọ̀ sí Eku Edewor (ọjọ́ìbí: 18 Oṣù Kejìlá, Ọdún 1986), jẹ́ òṣèrébìnrin, atọ́kùn ètò tẹlifíṣọ̀nù àti afẹwàṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi atọ́kùn ètò tẹlifíṣọ̀nù kan táa pè ní 53 Extra, èyí tí ó maá n jẹ́ gbígbé sáfẹ́fẹ́ lóri ìkànnì Africa Magic .

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

Wọ́n bí Edewor àti ìkejì rẹ̀ Kessiana ní Ilé-ìwòsàn Portland ní Ìlú Lọ́ndọ̀nù. Ìyá rẹ̀ tí n ṣe Juliana Edewor jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà. Bàbá rẹ̀ náà tí orúkọ rẹ̀ n ṣe Hugh Thorley, jẹ́ ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sí. Àwọn òbí Edewor kọrawọn sílẹ̀ nígbàtí ó wà lọ́mọdé, àwọn méjèjì sì tún ìgbeyàwó ṣe pẹ̀lú ẹlòmíràn. Ọkọ tí ìyá rẹ̀ padà fẹ́ ti di olóògbé.

Edewor dàgbà ní Nàìjíríà àti Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Ó gbé ní ìlú Èkó títí ó fi pé ọmọ ọdún mẹ́tàlá, níbi tí ó ti ní ètò-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ láti ilé-ìwé St. Saviour's School àti ilé-ìwé Grange School. Lẹ́hìn náà Edewor padà sí Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, níbi tí ó ti lọ sí ilé-ìwé Benenden School for Girls.

Edewor gba oyè-ẹ̀kọ́ ní ọdún 2008 nínu ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti eré ìtàgé láti Warwick University tó wà ní ìlú Coventry. Lẹ́hìn náà, ó kẹ́kọ̀ọ́ eré fíìmù ṣíṣe fún oṣù mẹ́ta ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga New York Film Academy ní ọdún 2009.

Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀

Edward kọ́kọ́ ṣàfihàn nínu tẹlifíṣọ̀nù ní ọdún 2006 nígbà tí ó fi díje níbi Britain’s Next Top Model. Ó kópa nínu àwọn sinimá àgbéléwò ní àkókó ìgbà tí ó n kàwé lọ́wọ́.Ó kópa nínu fíìmù ọdún 2010 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Sex & Drugs & Rock & Roll.

Àwọn ìtọ́kasí


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Eku Edewor by Wikipedia (Historical)


Who's the boss


Who's the boss


Ta ni Ọ̀gá náà jẹ́ fíìmù olólùfẹ́-apanilẹ́rìn-ín ọdún 2020 Nàìjíríà tó di ṣíṣejáde, kíkọ àti darí láti ọwọ́ Chinaza Onuzo (Naz Onuzo) tó ma jẹ́ fíìmù àkọ́kọ́ tó má jẹ́ Olùdarí fún. Eré náà fi Sharon Ooja, Fúnké Akíndélé àti Blossom Chukwujekwu sẹ àwọn Òṣèré tó kópa Olórí. Fíìmù náà di wíwò fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ọjọ́ Kẹrìndínlógún oṣù kejì, ọdún 2020 ní Èkó. Fíìmù náà jáde ní tíátà ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, ọdún 2020 àti tó sì rí ìròyìn gidi tó fi di àṣeyọrí ní Ọ́fíìsì tíkẹ́ẹ̀tì (box office).

Ipa àwọn Òṣèré

  • Sharon Ooja gẹ́gẹ́ bí Liah
  • Funke Akindele gẹ́gẹ́ bí Hauwa
  • Blossom Chukwujekwu gẹ́gẹ́ bí Lekan
  • Ini Dima-Okojie gẹ́gẹ́ bí Jùmọ̀kẹ́
  • Beverly Osu
  • Bolly Lomuo
  • Táyọ̀ Fáníran

Ìtàn ní sórí

Liah (Sharon Ooja), tó jẹ́ Aláṣẹ ọdọ́ aṣojú ìgbìmọ̀ ìpolówó kan tí wọ́n kàńpá fún láti má jẹ́ kí Ọ̀ga rẹ̀ mọ̀ ìgbà tí iṣẹ́-ráńpẹ́(side hustle) rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ àti àjọ asojú náà bá gba iṣẹ́ ńlá. Nǹkan tó ti ń bàjẹ́ tẹ́lẹ̀ wá bẹ̀rẹ̀ sí ní bàjẹ́ púpọ̀ si bẹ́ẹ̀ náà dè ni arábìnrin yìí bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àṣeyọrí si àti wí pé kò gbọ́dọ̀ jẹ́ kọ́gàá rẹ̀ mọ̀.

Ṣíṣejáde

Lára àwọn olùdásílẹ̀ Inkblot Productions, Chinaza Onuzo tí àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ fún aáyan rẹ̀ fún àwọn eré tó gbajúmọ̀ tó ti kọ gẹ́gẹ́ bí The Wedding Party 2, New Money àti The Set Up tó jẹ́ eré àkọ́kọ́ tó ṣe olùdarí látara rẹ̀ àti wí pé ó kéde rẹ̀ l'ori ínsíírágàmù. Fíìmù yìí jẹ́ fíìmù Kejìlá tó ma jẹ́ ṣíṣejáde lábẹ́ bánà ṣíṣejáde Inkblot Productions. Aláṣẹ vídíò ìfanilójú kékeré fíìmù jáde ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní, ọdún 2020.

Ìtọ́kasí

Giuseppe Zanotti Luxury Sneakers


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Who's the boss by Wikipedia (Historical)


Catching Feelings (fiimu)


Catching Feelings (fiimu)


Catching Feelings jẹ fiimu ere ere romantic 2017 South Africa kan ti a kọ, ti iṣelọpọ ati oludari nipasẹ Kagiso Lediga . It stars Lediga, Pearl Bayi, Andrew Buckland, Akin Omotoso, Precious Makgaretsa, Kate Liquorish, Tessa Jubber ati Loyiso Gola. The film was released on 9 March 2018, by United International Pictures and Ster-Kinekor. A ti tu fiimu naa silẹ lori 9 Oṣu Kẹta 2018, nipasẹ Awọn aworan United International ati Ster-Kinekor . [4] Fiimu naa wa lati san kaakiri agbaye lori 18 May 2018, nipasẹ Netflix ..

Idite

Fiimu naa tẹle itan ti “awọn ọmọ ile-iwe ọdọ ilu ati iyawo rẹ ti o lẹwa, bi igbesi aye wọn ṣe yipada nigbati ayẹyẹ ayẹyẹ ati onkọwe agbalagba hedonistic gbe sinu ile Johannesburg wọn pẹlu wọn”.

Simẹnti

  • Kagiso Lediga as Max Matsane
  • Pearl Bayi bi Samkelo
  • Akin Omotoso bi Joel
  • Makgaretsa iyebiye bi Lazola Yoko
  • Andrew Buckland bi Heiner Miller
  • Zandile Tisani bi Kabelo
  • Kate Liquorish bi Tabitha
  • Tyson Cross bi Miles
  • Tessa Jubber bi Nicole
  • Loyiso Gola bi Zweli

Ṣiṣejade

A ya fiimu naa ni Cape Town ati Johannesburg, South Africa, ni ọdun 2016. O ti wa ni igbẹhin si iranti ti John Volmink, a South African filmmaker ti o ku ni 2017.

Tu silẹ

Fiimu naa ṣe afihan ni 2017 Los Angeles Film Festival ni 18 Okudu 2017. A ti tu fiimu naa silẹ ni ọjọ 9 Oṣu Kẹta ọdun 2018 ni South Africa. Lori 18 May 2018, fiimu naa wa lati san kaakiri agbaye lori Netflix .

Gbigbawọle

Awọn fiimu ti gba ọjo agbeyewo lati alariwisi. Lori oju opo wẹẹbu aggregator atunyẹwo, Awọn tomati Rotten, fiimu naa ni idiyele ifọwọsi ti 100% da lori awọn atunwo 7, pẹlu iwọn iwuwo ti 7.25 / 10. .

Fiimu alariwisi Phumlani S. Langa of City Press South Africa fun awọn fiimu mẹrin irawọ jade ninu marun, wipe "Lediga ati Bayi mejeeji fi ri to ṣe ni yi didara ati ara gbóògì . Eleyi jẹ jasi ayanfẹ mi Bayi pic. [O] yoo kekere kan. bi ara ẹni Ayebaye, [Woody Allen ká] Midnight i Paris, lai irokuro aspect. Nitootọ, o jẹ agbegbe ati lekker. "

Giuseppe Zanotti Luxury Sneakers

Awọn itọkasi

Ita ìjápọ

  • Catching Feelings (fiimu) , (Netflix)
  • Catching Feelings , (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)

Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Catching Feelings (fiimu) by Wikipedia (Historical)






Text submitted to CC-BY-SA license. Source: by Wikipedia (Historical)






Text submitted to CC-BY-SA license. Source: by Wikipedia (Historical)






Text submitted to CC-BY-SA license. Source: by Wikipedia (Historical)


INVESTIGATION